Iṣe aago titunṣe ni Bala Muhammad n ṣe niluu Kaduna, ni Naijiria. Ti ẹ ba wọ inu ṣọọbu rẹ, oniruru aago atijọ ati aago aye ode oni ni ẹ maa ba ninu ṣọọbu naa. Ọkan lara awọn agbegbe ti ero maa n pọ si ...